It your boy hotmale
Oh yeah,yeah (habba)
Hun hun hun
Happy boy Izick Burna
Hun,Hun
Awón ómó òrò ń gbá òwò ópóló awón pópó ń gbá(Awón pópó ń gbá)
If you wanna live in the streets you most to lógbá ooo(You most to lógbá)
Ómó butty ń gbá ówó daddy awón Igbóró ń gbá(Awón Igbóró ń gbá)
Awón Igbóró ń gbá(Awón Igbóró ń gbá)
Má whine mì(Má whine mì)
Tobá lòwò shò Yámi(Tobá lòwò shò Yámi)
Tòna Badi shò clear ni
Tò ówó batań shó guard mi(shó guard me)
Ani rin árin fi ésé si
Hot and burna ma gbè Igèsi
Mio gbó oyinbo mafi iyèn si
But to bajé kudi ma gbó iyén si
It hard for me allah walahi
I bomb ig I bomb snap
I Carry client come WhatsApp
I collect wire Popo bà dèè
Popo arrest hustler
Hustler no carry wealth
But,hustler ni muscle ńla
(hustler ni muscle ńla)
Tobà ri red jacket ko jápá
Ni gba tó fé tókúlá
I get the lyric for belle
I get verse for cooler
Different patterns Lorin mi
Abi you sabi this formula
My Padi told me about tayo
Wón ló ómó yén lomu ńlá
Awón ómó òrò ń gbá òwò ópóló awón pópó ń gbá
If you wanna live in the street you most to lógbá ooo
Ómó butty ń gbá ówó daddy awón Igbóró ń gbá,Awón Igbóró ń gbá
Ayy You know the life that I live
I just dey alone do all my thing
Na wetin go be go be
Ani rógún kosi kosi oo
E go be oo(E go be oo)
Believe me oo( believe me oo)
Shà amin oo,amen,
(amen)amen(amen)
All this popo con dey chase us
Blood of Jesus cover everybody(cover everybody)
I no fit tell my mommy tin ba délé
E no go funny eeh
Oya wetin I go tell mama
Yahoo Lán sè nigbá tebi ń páwá
Na You dey beaf my matter
And I no really send your papa oo
Awón ómó òrò ń gbá òwò ópóló awón pópó ń gbá(Awón pópó ń gbá)
If you wanna live in the streets you most to lógbá ooo(You most to lógbá)
Ómó butty ń gbá ówó daddy awón Igbóró ń gbá(Awón Igbóró ń gbá)
Awón Igbóró ń gbá(Awón Igbóró ń gbá)
Written by: Abdulazeez Qudus, Oladosu isaac olayinka